Soulé Onimẹlẹ

Printer-friendly versionPrinter-friendly versionSend by emailSend by email

NI igba kanri, ọmọ ọkunrin kan wa ti orukọ rẹ njẹ Soulé, o n gbe pẹlu iya rẹ ni abule kan. Wọn toṣi pupọ, iya arugbo yii maa n ri ounjẹ ojo nipa hihun aṣọ, ṣugbọn Soulé ya imẹlẹ pupọ ti ko mọ ju ere lọ lojojumọ. Wọn wa npe ni Soulé Onimẹlẹ. Kosi ohun ti iya rẹ le mu ki o ṣe fun ohun, o wa sọ fun nikẹhin, lọjọkan, pe bi ko ba bẹrẹ ni ṣiṣẹ fun ounjẹ ara rẹ ohun yoo le jade ati kuro nile.
Soulé nitorin naa, jade kuro nile lọjọ keji o si fi ara rẹ ṣiṣẹ fun epinni ni ọdọ aladugbo wọn agbẹ; ṣugbọn bi o ti nbọ nile, niwọn igba ti koiti ni owo ri, o sọnu nigba ti o n gba ibi odo kekere kan kọja.
"Iwọ oponu ọmọ ọkunrin," iya rẹ wi, "o yẹ ki o fi si apo rẹ."
"Maa ṣe bẹẹ nigba miiran, mama" Soulé dahun.
Ni ọjọ keji, Soulé tun jade lọ lati ṣiṣẹ fun olutọju maalu, ti o fun ni ikoko wara kekere fun iṣẹ oojọ rẹ. Soulé gba ikoko wara o si mu sinu apo aṣọ rẹ nla bi iya rẹ ti sọ fun, gbogbo rẹ danu, ki o to de ile.
"Iwa omugọ l’owu", mama rẹ wi; "oyẹ ki o gbe lori rẹ ni."
"Maa ṣe bẹẹ nigba miiran, mama" Soulé dahun.
Bakanna ni ọjọ ti o tẹle, Soulé lọ ṣiṣẹ fun agbẹ kan, ti o pinnu lati fun ni abọ ọka bàbà kan. Ni irọlẹ, Soulégbe abọ ọka bàbà, o gbe lori lọ ile. Nigba ti o dele, kosi ohunkohun ninu abọ mọ, nitori awọn ẹyẹ ti ṣaa jẹ lori rẹ.
"Iwa omugọ alailọgbọn", mama rẹ wi; "oyẹ ki o rọra gbe lọwọ rẹ ni."
"Maa ṣe bẹẹ nigba miiran, mama" Soulé dahun.
Ni ọjọ keji, Soulé Onimẹlẹ tun jade lọ, o lọ ṣiṣẹ fun adinkara kan, ti o fun ni aja kekere kan. Soulé mu aja naa, o rọra n gbe kiri ni ọwọ rẹ, ṣugbọn aja na gejẹ gidi ti o fi fi silẹ ki o lọ. Nigba ti o dele, iya rẹ sọfun,
"Iwọ oponu eniyan, oyẹ ki o fi okun so ni, ki o si fa bi o ti nbọ nile. "
"Maa ṣe

Language:

Download TXT: 
Download PDF: 
Download ANDROID app: 
Download AUDIO: 

File types:

Facebook Comments Box

Public Domain Mark 1.0
This @dc:type-name, @dc:title, by @cc:attributionName, is free of known copyright restrictions.

Tell Us A Story !

Files must be less than 8 MB.
Allowed file types: mp3 wav wma.
Leave blank to use trimmed value of full text as the summary.
Description of story
Type your name here
Type Your Email Here
Upload a replacement picture for your story
Files must be less than 64 MB.
Allowed file types: png gif jpg jpeg.
CAPTCHA
This question is for testing whether you are a human visitor and to prevent automated spam submissions.
Image CAPTCHA
Enter the characters shown in the image.

Vertical Tabs