Soulé Onimẹlẹ: Page 2 of 2

Printer-friendly versionPrinter-friendly versionSend by emailSend by email

bẹẹ nigba miiran, mama" Soulé dahun.
Bakanna ni ọjọ ti o tẹle, Soulé lọ ṣiṣẹ fun alapata kan, ti o fun ni ẹran gige nla kan. Soulé nu ẹran naa, o so mọ okun, o si fa nilẹ tẹle ara rẹ bi o ti nlọ, ti o fijẹ pe nigba ti o dele, ẹran naa ti bajẹ patapata. Inu bi iya rẹ gidigidi si bayi, nitori ọjọ Aiku ni ọjọ keji, kosi si ohun miiran nile fun jijẹ yatọ si ewebe fun ounjẹ alẹ.
"Iwọ alainironu," iya rẹ wi fun ọmọ rẹ; "o yẹ ki o gbe si ejika rẹ ni."
"Maa ṣe bẹẹ nigba miiran, mama" Soulé dahun.

Ni ọjọ keji, Soulé Onimẹlẹ tun jade lẹẹkansi, osi fi ara rẹ ṣiṣẹ lọdọ olutọju ẹran ọsin, ẹni ti o fun ni kẹtẹkẹtẹ nitori laala rẹ. O ṣoro fun Soulé lati gbe kẹtẹkẹtẹ yi si ejika rẹ, ṣugbọn o ri bẹẹ ṣe, o si bẹrẹ sini rin diẹdiẹ lọ ile pẹlu kẹtẹkẹtẹ ni ejika rẹ.
Ni oju ọna, ọkunrin ọlọrọ kan wa pẹlu ọmọbinrin rẹ kan ṣoṣo, ọmọbinrin ti o rẹwa, ti o diti kosi le sọrọ. Ọmọbinrin yi ko rẹrin ri ni aye rẹ, dọkita sini koni sọrọ ayafi bi ẹnikan ba mu rẹrin. Ọmọbinrin yi n wo oju ferese nigba ti Soulé nkọja pẹlu kẹtẹkẹtẹ ni ejika rẹ, pẹlu ẹsẹ loke lala, iri yii yatọ o si pani lẹrin ti ọmọbinrin yii fib u jade pẹlu ẹrin, lẹsẹkẹsẹ lole gbọran ti o si le sọrọ pada.
Inu baba rẹ dun gidigidi, o mu ileri rẹ ṣẹ nipa fifun gẹgẹbi aya fun Soulé Onimẹlẹ, ẹni ti o di ọlọrọ. Wọn gbe inu ile nla, iya Soulé sig be pẹlu wọn ninu idunnu nla.

- Rotimi Ogunjobi ni o ṣẹda rẹ

Language:

Download TXT: 
Download PDF: 
Download ANDROID app: 
Download AUDIO: 

File types:

Facebook Comments Box

Public Domain Mark 1.0
This @dc:type-name, @dc:title, by @cc:attributionName, is free of known copyright restrictions.

Tell Us A Story !

Files must be less than 8 MB.
Allowed file types: mp3 wav wma.
Leave blank to use trimmed value of full text as the summary.
Description of story
Type your name here
Type Your Email Here
Upload a replacement picture for your story
Files must be less than 64 MB.
Allowed file types: png gif jpg jpeg.
CAPTCHA
This question is for testing whether you are a human visitor and to prevent automated spam submissions.
Image CAPTCHA
Enter the characters shown in the image.

Vertical Tabs