Àwọn Ọkùnrin Afọ́jú Mẹ́fà Àti Erin Náà.

Printer-friendly versionPrinter-friendly versionSend by emailSend by email

Àwọn ọkùnrin afọ́jú méfà kan wà tí ó maa ń dúró lẹ́bà ọ̀nà lójojúmọ́, wọ́n maa ń ṣagbe lówọ́ àwọn to bá n kọjá. Wọ́n ti gbọ́ nípa erin tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n wọn kòrí ọ̀kan rí; níwọ̀n ìgbà tí wọ́n jẹ́ afọ́jú.
Wọn bẹ ọrẹ wọn ni ọjọ kan lati mu wọn lọ ibi wọn nko awọn ẹranko si ati ibi ti wọn tọju erin si. Nigba ti wọn sọ fun wọn pe ẹranko naa wa niwaju wọn, inu wọn dun gidigidi. Ṣugbọn niwọn igba ti wọn koleri erin naa pẹlu oju wọn ṣugbọn wọn rope nipa fifi ọwọ kan wọn le kọ irufẹ ẹranko ti o jẹ. Nitori naa, wọn rọ oluṣọ ibi ti wọn nko ẹranko si lati gba wọn laye lati wọ ibi ti wọn ko erin si ati sunmọ ẹranko naa.
Ẹni akọkọ fi ọwọ rẹ si ẹgbẹ erin naa. "Bẹẹni, bẹẹni!" oni, "Bayi mo mọ oun gbogbo nipa erin yii. Bii ogiri lori."
Ẹnikeji fọwọ kan ehin erin naa. "Arakunrin mi," oni, "O ṣaṣiṣe. Kori bi ogiri rara. Ori roboto, o ndan o si mu. O jọ ida ju ohun gbogbo lọ."
Ẹnikẹta pinnu lati di ọwọ ija erin mu. "Ẹyin mejeji lo ṣaṣiṣe," oni. "Ẹnikẹni ti o mọ ohun loleri pe erin jọ ejo."
Ẹnikẹrin na ọwọ rẹ, o si gba ọkan lara ẹsẹ erin mu. "O,ẹma fọju o!" oni. "O han gedegbe simi pe ori roboto, o ga gẹgẹbi igi."
Ẹnikarun jẹ ẹni giga, o wa ni anfaani lati di eti erin mu. "Ẹni ti oju rẹ fọju gbọdọ mọ pe ẹranko yii o jọ nnkan lara awọn ohun ti ẹ darukọ, "oni. "O dabi abẹbẹ nla ni."
Ẹnikẹfa fọju lotitọ, o gba ni akoko diẹ ki o to ri eriin rara. Amọṣa o di iru ẹranko mu.
"Ẹyin ẹgbẹ ope!" o kigbe. "Ẹti oadanu oye yin. Erin yii o jọ ogiri, tabi ikọ, tabi ejo, tabi igi; bẹẹni kiiṣe abẹbẹ. Ẹnikẹni ti o ni oye rara leri pe o jọ okun."
Nigba naa erin rin kuro lọdọ wọn, asi mu awọn afọju mẹfa yii lọ joko lori aga ninu ile ibi a nko ẹranko si. Bi wọn ti joko wọn ṣi tẹsiwaju pẹlu awọn ariyanjiyan wọn nipa erin. Ọkankan lo gbagbọ pe ohun mọ bi ẹrank o naaa

Language:

Download TXT: 
Download PDF: 
Download ANDROID app: 
Download AUDIO: 

File types:

Facebook Comments Box

Public Domain Mark 1.0
This @dc:type-name, @dc:title, by @cc:attributionName, is free of known copyright restrictions.

Tell Us A Story !

Files must be less than 8 MB.
Allowed file types: mp3 wav wma.
Leave blank to use trimmed value of full text as the summary.
Description of story
Type your name here
Type Your Email Here
Upload a replacement picture for your story
Files must be less than 64 MB.
Allowed file types: png gif jpg jpeg.
CAPTCHA
This question is for testing whether you are a human visitor and to prevent automated spam submissions.
Image CAPTCHA
Enter the characters shown in the image.

Vertical Tabs